OneTV.ng

Gbangbadekun: Eto Aabo, Ojuse Àwọn Ọ̀dọ́

Lagos Television

Kí ni ojúṣe àwọn ọ̀dọ́ nínú mímú àlàáfíà àti ààbò wà ní àwùjọ wa? Nínú ẹ̀yà yìí ti Gbangbadekun, a jíròrò bí àwọn ọdọ ṣe lè kópa rere nínú ìdàgbàsókè àwùjọ, ìtọju ààbò, àti bí wọ́n ṣe lè di alábàápín nínú ìmúlẹ̀ àlàáfíà.