Gbangbadekun: Isakoso Egbe Onimoto pelu Alejo Musiliu Akinsanya (MC…
Lagos Television
Ẹ darapọ mọ wa lori Gbangbadekun fun ijiroro pataki pelu Alejo, Musiliu Akinsanya (MC Oluomo), lati sọ nipa iṣakoso, idagbasoke agbegbe, ati ipa Egbe Onimoto ninu awujọ.