OneTV.ng

Káàárọ̀ O-o-jiire: Àtúnyẹ̀wò Ìṣẹ́ Àtẹ́yìnwá

Lagos Television

Nínú àtẹ̀jáde yìí, a ń ṣe àtúnyẹ̀wò àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ àti iṣẹ́ pàtàkì tó ti wáyé, pẹ̀lú àwọn kókó tó yẹ ká rántí àti àwọn ẹ̀kọ́ tá a lè kọ́ láti inú wọn. Ẹ wo Káàárọ̀ O-o-jiire lórí Lagos Television fún ìjíròrò àti àlàyé tó kúnrẹ́rẹ́.