OneTV.ng

Kaaro O-o-jiire: Arun Ebola — Ibasepọ̀ láàárín ènìyàn, ẹranko àti…

Lagos Television

Arun Ebola jẹ́ àrùn tó léwu tó sì lè tàn láti ẹranko sí ènìyàn àti láti ènìyàn sí ènìyàn. Báwo ni ìbáṣepọ̀ láàárín ènìyàn, ẹranko àti àyíká ṣe lè ní ipa lórí ìtànkálẹ̀ àrùn yìí? Kí ni ipa tí ìmọ́tótó àyíká àti ìlera gbogbo ènìyàn lè kó nínú dídènà rẹ̀?