OneTV.ng

Kaaro O-o-jiire: Eko, owe Yoruba ati itumo won

Lagos Television

Ninu atejade yii ti Kaaro O-o-jiire, a n wo awon owe Yoruba, itumo won ati bi a se le lo won ninu aye ojoojumọ. Darapo mo wa lati tun awon owe ati asa Yoruba mo, ki a si maa pa ede ati asa wa mo.