OneTV.ng

Kaaro O-o-jiire: Isoro Igbeyawo – Fara da a, soro nipa re, abi wa…

Lagos Television

Ìgbéyàwó ní àwọn ìpèníjà tirẹ̀, ṣùgbọ́n báwo ló yẹ kí tọkọtaya ṣe kojú wọn? Ṣé ó yẹ kí ènìyàn fara da gbogbo ìṣòro tó bá yọjú nínú ìgbéyàwó, bá a sọ̀rọ̀ pẹ̀lú alábàágbé rẹ̀, tàbí kí ó wá ọ̀nà àtúnṣe mìíràn?