Kaaro O-ojiire: Àṣà àti Ìwà Láàárín Ìran Àtijọ́ àti Ìran Òde Òní: Kí…
Lagos Television
Káàrọ̀ Oòjíire ṣàyẹ̀wò Àṣà àti Ìwà láàárín ìran àtijọ́ àti ìran òde òní. Kí ni ó ti yípadà nínú àṣà, ìwà, àti ọ̀nà ìgbésí ayé àwọn ọmọ Yorùbá? Nínú ìjíròrò yìí, a máa wo bí àṣà àti ìwà ṣe ń yí padà láti ìran kan sí òmíràn, àwọn ohun tí ìran àtijọ́ fi sílẹ̀ fún wa, àti ipa tí ìgbésí ayé òde òní ń…