Kaaro O-ojiire: Diphtheria - Mo Awon Ami Re, Dena Itankale Re
Lagos Television
Nínú àtẹ̀jáde yìí, a ń sọ̀rọ̀ nípa Diphtheria (Dífítíríà) — àrùn tó lèwu tí ó sì lè tàn láti ènìyàn kan sí ẹlòmíràn. A máa wo: Àwọn àmì àti àpẹẹrẹ Diphtheria. Bí àrùn náà ṣe ń tàn. Àwọn ọ̀nà tí a lè gbà dènà ìtànkálẹ̀ rẹ̀. Ìdí tí ajesara fi ṣe pàtàkì nínú dídènà àrùn náà.