OneTV.ng

Kaaro O-Ojiire: Idibo 2027 - Ki Ni Awon Oludibo Gbodo Maa Beere Fun?

Lagos Television

Báwo ni àwọn aráàlú ṣe lè lo agbára ìdìbò wọn dáadáa ní ìdìbò 2027? Nínú àtẹ̀jáde yìí, a máa ń wo àwọn ohun pàtàkì tí àwọn olùdìbò yẹ kí wọ́n béèrè lọ́wọ́ àwọn olóṣèlú àti àwọn tó ń wá àṣẹ.