Kaaro O-ojiire: Ikolu Ikoriira Si Awon Omo Naijiria Ni South Africa
Lagos Television
Ninu eto oni, a wo bi ikolu ikorira si awon omo Naijiria ati awon ajeji miran se n tesiwaju ni orile-ede South Africa. Kini idi gangan to n fa wahala yii? Ipa wo ni o n ni lori igbesi aye awon eniyan wa nibẹ? A tun gbo ero awon araalu ati awon amoye lori bi a se le wa ojutu to peye.