OneTV.ng

Kaaro O-ojiire: Ipa Àwọn Òbí Nínú Ìgbéyàwó

Lagos Television

Nínú àkòrí “Ipa Àwọn Òbí Nínú Ìgbéyàwó”, a máa jíròrò nípa ipa tí àwọn òbí lè ní nínú ìgbéyàwó àwọn ọmọ wọn. Ṣé àwọn òbí yẹ kí wọ́n ní ipa tó pọ̀ nínú ìgbéyàwó ọmọ wọn? Kí ni ààlà tó yẹ kí wọ́n má kọjá?