OneTV.ng

Kaaro O-ojiire: Ipolongo Idibo 2027 - Ki Ni E N Reti?

Lagos Television

Ìpolongo Ìdìbò 2027 — Kí ni ẹ̀ ń retí? Bí ìdìbò 2027 ṣe ń sún mọ́lé, ọ̀pọ̀ ìbéèrè ń wá sí ọkàn àwọn aráàlú. Kí ni ẹ̀ ń retí láti ọ̀dọ̀ àwọn olùdíje? Kí ni àwọn kókó pàtàkì tí ẹ fẹ́ kí wọ́n gbé kalẹ̀? Báwo ni a ṣe lè ní ìdìbò tó ṣe kedere, tó sì jẹ́ àlàáfíà?