OneTV.ng

Káàrọ̀ O-Ojíire: Ìsọjí Itagbangba Taberea 2026 – Má Ṣe Bẹ̀rù

Lagos Television

Nínú àkòrí “Má Ṣe Bẹ̀rù”, a ń rán ara wa létí pé, bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé ìpèníjà, ìṣòro àti àwọn ohun tí a kò mọ̀ lè wà níwájú wa, a kò gbọ́dọ̀ jẹ́ kí ẹ̀rù gba ọkàn wa. Jẹ́ kí ọ̀rọ̀ Ọlọ́run fún ọ ní ìgboyà, kí o sì gbẹ́kẹ̀lé Rẹ̀ nínú gbogbo ipò.