OneTV.ng

Káàrọ̀ Òjíire: Gbigbe Orin Ìbílẹ̀ Wa Lárugẹ Ní Agbaye

Lagos Television

Nínú àkànṣe àkòrí yìí, a ń ṣàgbéyẹ̀wò bí orin ìbílẹ̀ Yorùbá ṣe ń gba àyè pàtàkì lórílẹ̀-èdè àti kárí ayé. A máa wo ipa àwọn akọrin, àwọn olùgbéga àṣà, àti àwọn olólùfẹ́ orin tí ń ṣiṣẹ́ takuntakun láti jẹ́ kí ogún orin wa má bàjẹ́.