Owón Gógó Owó Ata
Lagos Television
Owón gógó owó ata lásìkò yìí ti ń kan oúnjẹ ojoojúmọ́ àti ìnáwó ilé. Ìkò Kaaro O Jiire jáde sí orí pópó Ìlú Èkó láti gbọ́ èrò àwọn ará ìlú, kí wọ́n sì tún mọ bí wọ́n ṣe ń fara da àyípadà yìí