OneTV.ng

Yàrá Ìkẹ́kọ̀ọ́: Àwọn àpá ọ̀rọ̀ sísọ tí a ní nínú èdè Yorùbá

Lagos Television

Nínú èdè Yorùbá, àwọn àpá ọ̀rọ̀ sísọ jẹ́ ọ̀nà pàtàkì tí a fi ń sọ̀rọ̀ ní kíkún àti pẹ̀lú ìtumọ̀ tó jinlẹ̀. Nínú àtẹ̀jáde Yàrá Ìkẹ́kọ̀ọ́yìí, a máa wo oríṣiríṣi àpá ọ̀rọ̀ sísọ, ìtumọ̀ wọn àti bí a ṣe lè lò wọ́n dáadáa nínú èdè Yorùbá.